Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn ará ilẹ̀ Juda, ati ìdajì àwọn ọmọ Israẹli ti sin ọba kọjá odò, ọba lọ sí Giligali, Kimhamu sì bá a lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:40 ni o tọ