Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Dafidi dá Abiṣai ati Joabu ẹ̀gbọ́n rẹ̀ lóhùn pé, “Kí ló kàn yín ninu ọ̀rọ̀ yìí? Kí ni n óo ti ṣe yín sí, ẹ̀yin ọmọ Seruaya, tí ẹ̀ ń ṣe bí ọ̀tá sí mi? Èmi ni ọba Israẹli lónìí, ẹnìkan kò sì ní pa ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ Israẹli.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:22 ni o tọ