Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ìṣẹ́gun ọjọ́ náà pada di ìbànújẹ́ fún gbogbo àwọn eniyan; nítorí wọ́n gbọ́ pé ọba ń ṣọ̀fọ̀ ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:2 ni o tọ