Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìròyìn ohun tí àwọn eniyan Israẹli ń wí kan Dafidi ọba lára. Dafidi ọba ranṣẹ sí àwọn alufaa mejeeji: Sadoku, ati Abiatari, láti bèèrè lọ́wọ́ àwọn àgbààgbà Juda pé, “Kí ló dé tí ẹ fi níláti gbẹ́yìn ninu ètò àtidá ọba pada sí ààfin rẹ̀?

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:11 ni o tọ