Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahimaasi dáhùn pé, “Mo ṣá fẹ́ lọ ni, ohun yòówù tí ó lè ṣẹlẹ̀.”Joabu dáhùn pé, “Ǹjẹ́ bí o bá fẹ́, máa lọ.” Ahimaasi bá sáré gba ọ̀nà pẹ̀tẹ́lẹ̀ lọ, ó sì ṣáájú ará Kuṣi náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:23 ni o tọ