Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 18:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu bá sọ fún ọ̀kan ninu àwọn ará Kuṣi pé, “Lọ sọ ohun tí o rí fún ọba.” Ará Kuṣi náà bá tẹríba fún Joabu, ó sì sáré lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:21 ni o tọ