Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 17:29 BIBELI MIMỌ (BM)

oyin, omi wàrà, ati wàrà sísè. Wọ́n sì kó aguntan wá pẹlu, láti inú agbo wọn fún Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀, kí wọ́n lè rí nǹkan jẹ. Nítorí wọ́n rò pé yóo ti rẹ̀ wọ́n, ebi yóo ti máa pa wọ́n, òùngbẹ yóo sì ti máa gbẹ wọ́n, ninu aṣálẹ̀ tí wọ́n wà.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:29 ni o tọ