Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 17:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi dé Mahanaimu, Ṣobi, ọmọ Nahaṣi, wá pàdé rẹ̀, láti ìlú Raba, ní ilẹ̀ Amoni. Makiri, ọmọ Amieli, náà wá, láti Lodebari; ati Basilai, láti Rogelimu, ní ilẹ̀ Gileadi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:27 ni o tọ