Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 17:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ahitofeli rí i pé, Absalomu kò tẹ̀lé ìmọ̀ràn tí òun fún un, ó di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ní gàárì, ó pada lọ sí ìlú rẹ̀. Lẹ́yìn tí ó ti ṣètò ilé rẹ̀, ó pokùnso, ó bá kú; wọ́n sì sin ín sí ibojì ìdílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:23 ni o tọ