Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 17:2 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo kọlù ú nígbà tí àárẹ̀ bá mú un; tí ọkàn rẹ̀ sì rẹ̀wẹ̀sì; ẹ̀rù yóo bà á, gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ yóo sì sá lọ. Ọba nìkan ṣoṣo ni n óo pa.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:2 ni o tọ