Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 17:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani ati Ahimaasi dúró sí ibi orísun Enrogeli, ní ìgbèríko ati máa lọ sí Jerusalẹmu, nítorí pé ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ fojú kàn wọ́n, pé wọ́n wọ ìlú rárá. Iranṣẹbinrin kan ni ó máa ń lọ sọ ohun tí ó bá ti ṣẹlẹ̀ fún wọn, àwọn náà á lọ sọ fún Dafidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:17 ni o tọ