Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà, ẹ̀rù yóo ba àwọn tí wọ́n jẹ́ akikanju jùlọ ninu àwọn eniyan rẹ, tí wọ́n sì láyà bíi kinniun; nítorí pé, gbogbo eniyan ní Israẹli ni ó mọ̀ pé akọni jagunjagun ni baba rẹ, akikanju sì ni àwọn eniyan tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:10 ni o tọ