Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọba dáhùn pé, “Kò sí ohun tí ó kan ẹ̀yin ọmọ Seruaya ninu ọ̀rọ̀ yìí. Kí ni n óo ti ṣe yín sí, ẹ̀yin ọmọ Seruaya? Bí ó bá jẹ́ pé OLUWA ni ó sọ fún un pé kí ó máa ṣépè lé mi, ta ló ní ẹ̀tọ́ láti bèèrè pé, kí ló dé tí ó fi ń ṣe bẹ́ẹ̀?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 16

Wo Samuẹli Keji 16:10 ni o tọ