Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gẹ́rẹ́ tí Dafidi kọjá góńgó orí òkè náà, Siba, iranṣẹ Mẹfiboṣẹti pàdé rẹ̀, ó ń da àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ bíi mélòó kan bọ̀ tí ó di igba (200) burẹdi rù, pẹlu ọgọrun-un ṣiiri èso resini, ati ọgọrun-un ṣiiri èso tútù mìíràn ati àpò aláwọ kan tí ó kún fún ọtí waini.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 16

Wo Samuẹli Keji 16:1 ni o tọ