Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Absalomu á tún wá fi kún un pé, “A! Bí wọ́n bá fi mí ṣe adájọ́ ní ilẹ̀ yìí ni, bí ẹnikẹ́ni bá ní èdè-àìyedè kan pẹlu ẹlòmíràn, tabi tí ẹnìkan bá fẹ́ gba ohun tíí ṣe ẹ̀tọ́ rẹ̀, wọn ìbá máa tọ̀ mí wá, ǹ bá sì máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ fún wọn.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:4 ni o tọ