Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi gun òkè náà dé orí, níbi tí wọ́n ti máa ń rúbọ sí Ọlọ́run, Huṣai, ará Ariki, wá pàdé rẹ̀ pẹlu aṣọ rẹ̀ tí ó ti ya, ó sì ti ku eruku sí orí rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:32 ni o tọ