Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Absalomu ń rúbọ lọ́wọ́, ó ranṣẹ sí ìlú Gilo láti lọ pe Ahitofeli ará Gilo, ọ̀kan ninu àwọn olùdámọ̀ràn Dafidi ọba. Ọ̀tẹ̀ tí Absalomu ń dì ń gbilẹ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ náà ń pọ̀ sí i.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:12 ni o tọ