Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà wí fún ọba pé, “Kabiyesi, gbogbo ohun tí o bá ṣe nípa ọ̀rọ̀ yìí, èmi ati ìdílé mi ni a ni ẹ̀bi rẹ̀, ẹ̀bi rẹ̀ kò kan kabiyesi ati ìdílé rẹ̀ rárá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:9 ni o tọ