Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá bí i pé, “Ṣé Joabu ni ó rán ọ ní gbogbo iṣẹ́ tí o wá jẹ́ yìí, àbí òun kọ?”Obinrin náà dáhùn pé, “Kabiyesi, bí o ti bèèrè ìbéèrè yìí kò jẹ́ kí n mọ̀ bí mo ti lè yí ẹnu pada rárá. Òtítọ́ ni, Joabu ni ó kọ́ mi ní gbogbo ohun tí mo sọ, ati gbogbo bí mo ti ṣe.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:19 ni o tọ