Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 13:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn ń sá bọ̀ wálé, àwọn kan wá sọ fún Dafidi pé, “Absalomu ti pa gbogbo àwọn ọmọ rẹ, ati pé kò ṣẹ́ku ẹyọ ẹnìkan.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:30 ni o tọ