Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ̀rẹ̀ sí kó gbogbo àwọn ará ìlú náà ṣiṣẹ́. Àwọn kan ń lo ayùn, àwọn mìíràn ń lo ọkọ́ onírin, ati àáké onírin, àwọn mìíràn sì ń gé bulọọku, wọ́n ń sun ún. Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe sí àwọn ará ìlú Amoni yòókù. Lẹ́yìn náà, òun ati àwọn eniyan rẹ̀ pada sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:31 ni o tọ