Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dá wọn lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, nígbà tí ó wà láàyè, mo gbààwẹ̀, mo sì sọkún, pé bóyá OLUWA yóo ṣàánú mi, kí ó má kú.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:22 ni o tọ