Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 11:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi rán oníṣẹ́ náà sí Joabu pé, “Má ṣe jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yìí da ọkàn rẹ rú níwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé ẹnikẹ́ni kò lè mọ ẹni tí ogun yóo pa. Tún ara mú gidigidi, kí o sì gba ìlú náà.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 11

Wo Samuẹli Keji 11:25 ni o tọ