Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

inú lè bí i, kí ó sì bèèrè lọ́wọ́ rẹ pé, ‘Kí ló dé tí ẹ fi súnmọ́ ìlú náà tóbẹ́ẹ̀ láti bá wọn jà? Ẹ ti gbàgbé pé wọ́n lè bẹ̀rẹ̀ sí ta ọfà láti orí ògiri wọn ni?

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 11

Wo Samuẹli Keji 11:20 ni o tọ