Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kan, nígbà tí Dafidi jí lójú oorun, ó gun orí òrùlé ààfin rẹ̀. Bí ó ti ń rìn káàkiri níbẹ̀, ó rí obinrin kan tí ń wẹ̀, obinrin náà jẹ́ arẹwà gidigidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 11

Wo Samuẹli Keji 11:2 ni o tọ