Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 10:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ọba wí pé, “N óo ṣe ẹ̀tọ́ fún Hanuni, ọmọ Nahaṣi gẹ́gẹ́ bí baba rẹ̀ ti ṣe ẹ̀tọ́ fún mi.” Dafidi bá rán oníṣẹ́ lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ láti tù ú ninu, nítorí ikú baba rẹ̀.Nígbà tí àwọn oníṣẹ́ Dafidi dé Amoni,

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 10

Wo Samuẹli Keji 10:2 ni o tọ