Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 10:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì kó gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ yòókù sábẹ́ ọ̀gágun Abiṣai, tí ó jẹ́ arakunrin rẹ̀, Abiṣai bá fi olukuluku sí ipò rẹ̀, wọ́n dojú kọ àwọn ará Amoni.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 10

Wo Samuẹli Keji 10:10 ni o tọ