Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ̀yin òkè Giliboa,kí òjò má ṣe rọ̀ le yín lórí,bẹ́ẹ̀ ni kí ìrì má ṣe sẹ̀ sórí yín,kí èso kan má so mọ́ ní gbogbo orí òkè Giliboa,nítorí pé, ibẹ̀ ni apata àwọn akikanju ti dípẹtà;a kò sì fi òróró kun apata Saulu mọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 1

Wo Samuẹli Keji 1:21 ni o tọ