Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní ilẹ̀ Hadiraki yóo jìyà, bẹ́ẹ̀ náà sì ni ìlú Damasku. Nítorí pé OLUWA ló ni àwọn ìlú Aramu, bí ó ti ni àwọn ẹ̀yà Israẹli.

Ka pipe ipin Sakaraya 9

Wo Sakaraya 9:1 ni o tọ