Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

bẹ́ẹ̀ ni mo tún pinnu nisinsinyii láti ṣe ẹ̀yin ará Jerusalẹmu ati àwọn ará ilé Juda ní rere. Nítorí náà, ẹ má bẹ̀rù.

Ka pipe ipin Sakaraya 8

Wo Sakaraya 8:15 ni o tọ