Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe agídí, wọ́n kọ̀ wọn kò gbọ́ òfin ati ọ̀rọ̀ tí OLUWA àwọn ọmọ ogun fi agbára ẹ̀mí rẹ̀ rán sí wọn, láti ẹnu àwọn wolii. Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun bínú sí wọn gidigidi.

Ka pipe ipin Sakaraya 7

Wo Sakaraya 7:12 ni o tọ