Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 6:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn tí wọ́n wà ní ọ̀nà jíjìn réré yóo wá láti ba yín kọ́ ilé OLUWA. Ẹ óo wá mọ̀ dájú pé OLUWA àwọn ọmọ ogun ni ó rán mi si yín. Gbogbo nǹkan wọnyi yóo ṣẹ patapata bí ẹ bá pa òfin OLUWA Ọlọrun yín mọ́.”

Ka pipe ipin Sakaraya 6

Wo Sakaraya 6:15 ni o tọ