Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti gbé ojú sókè ni mo rí àwọn obinrin meji tí wọn ń fi tagbára tagbára fò bọ̀, ìyẹ́ apá wọn dàbí ìyẹ́ ẹyẹ àkọ̀. Wọ́n hán agbọ̀n náà, wọ́n sì ń fò lọ.

Ka pipe ipin Sakaraya 5

Wo Sakaraya 5:9 ni o tọ