Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bi mí pé kí ni mo rí.Mo dáhùn pé, “Mo rí ọ̀pá fìtílà wúrà, àwo kan sì wà lórí rẹ̀. Fìtílà meje wà lórí ọ̀pá náà, fìtílà kọ̀ọ̀kan sì ní òwú fìtílà meje.

Ka pipe ipin Sakaraya 4

Wo Sakaraya 4:2 ni o tọ