Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí o bá tẹ̀lé ọ̀nà mi, tí o sì pa òfin mi mọ́, o óo di alákòóso ilé mi ati àwọn àgbàlá rẹ̀. N óo sì fún ọ ní ipò láàrin àwọn tí wọ́n dúró wọnyi.

Ka pipe ipin Sakaraya 3

Wo Sakaraya 3:7 ni o tọ