Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè ni yóo parapọ̀ láti di eniyan mi nígbà náà. N óo máa gbé ààrin yín; ẹ óo sì mọ̀ pé èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo ranṣẹ si yín.

Ka pipe ipin Sakaraya 2

Wo Sakaraya 2:11 ni o tọ