Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Tó bá di ìgbà náà, àwọn odò tí wọ́n kún fún omi ìyè yóo máa ṣàn jáde láti Jerusalẹmu. Apá kan wọn yóo máa ṣàn lọ sinu òkun tí ó wà ní ìwọ̀ oòrùn, apá keji yóo máa ṣàn lọ sí òkun tí ó wà ní ìlà oòrùn, yóo sì máa rí bẹ́ẹ̀ tòjò-tẹ̀ẹ̀rùn.

Ka pipe ipin Sakaraya 14

Wo Sakaraya 14:8 ni o tọ