Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 14:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá ṣe pé àwọn ará Ijipti ni wọ́n kọ̀ tí wọn kò wá síbi Àjọ̀dún Àgọ́ náà, irú àrùn tí OLUWA fi bá àwọn orílẹ̀-èdè tí wọn kò wá sí ibi Àjọ Àgọ́ jà, ni yóo dà lé wọn lórí.

Ka pipe ipin Sakaraya 14

Wo Sakaraya 14:18 ni o tọ