Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 10:10 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo kó wọn pada sí ilẹ̀ wọn láti ilẹ̀ Ijipti wá,n óo kó wọn jọ láti ilẹ̀ Asiria;n óo sì kó wọn wá sí ilẹ̀ Gileadi ati ilẹ̀ Lẹbanoni,wọn óo kún ilẹ̀ náà tóbẹ́ẹ̀ tí kò fi ní sí ààyè mọ́.

Ka pipe ipin Sakaraya 10

Wo Sakaraya 10:10 ni o tọ