Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sakaraya 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

mo sì bèèrè ìtumọ̀ ohun tí mo rí lọ́wọ́ angẹli tí ń bá mi sọ̀rọ̀.Ó bá dá mi lóhùn pé, “Àwọn ìwo wọnyi dúró fún àwọn alágbára ayé tí wọ́n fọ́n Juda, Israẹli, ati Jerusalẹmu ká.”

Ka pipe ipin Sakaraya 1

Wo Sakaraya 1:19 ni o tọ