Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Boasi bá fi kún un pé, “Ọjọ́ tí o bá ra ilẹ̀ yìí ní ọwọ́ Naomi, bí o bá ti ń ra ilẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni óo ra Rutu, ará ilẹ̀ Moabu, opó ọmọ Naomi; kí orúkọ òkú má baà parun lára ogún rẹ̀.”

Ka pipe ipin Rutu 4

Wo Rutu 4:5 ni o tọ