Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Boasi bá ṣú Rutu lópó, Rutu sì di aya rẹ̀. Nígbà tí Boasi bá a lòpọ̀, ó lóyún, ó bí ọmọkunrin kan.

Ka pipe ipin Rutu 4

Wo Rutu 4:13 ni o tọ