Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Boasi jẹ, tí ó mu tán, tí inú rẹ̀ sì dùn, ó lọ sùn lẹ́yìn òkítì ọkà Baali tí wọ́n ti pa. Rutu bá rọra lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó ṣí aṣọ kúrò ní ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì sùn tì í.

Ka pipe ipin Rutu 3

Wo Rutu 3:7 ni o tọ