Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Naomi bá dáhùn, ó ní, “Fara balẹ̀ ọmọ mi, títí tí o óo fi gbọ́ bí ọ̀rọ̀ náà yóo ti yọrí sí; nítorí pé ara ọkunrin yìí kò ní balẹ̀ títí tí yóo fi yanjú ọ̀rọ̀ náà lónìí.”

Ka pipe ipin Rutu 3

Wo Rutu 3:18 ni o tọ