Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Rutu bá sùn lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀ títí di òwúrọ̀ ọjọ́ keji, ṣugbọn ó tètè dìde ní àfẹ̀mọ́jú, kí eniyan tó lè dá eniyan mọ̀. Boasi bá kìlọ̀ fún un pé, “Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ mọ̀ pé o wá sí ibi ìpakà.”

Ka pipe ipin Rutu 3

Wo Rutu 3:14 ni o tọ