Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Rutu dìde, láti tún máa ṣa ọkà, Boasi pàṣẹ fún àwọn ọdọmọkunrin rẹ̀, ó ní, “Ẹ jẹ́ kí ó máa ṣa ọkà láàrin àwọn ìtí ọkà tí ẹ dì jọ, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ yọ ọ́ lẹ́nu.

Ka pipe ipin Rutu 2

Wo Rutu 2:15 ni o tọ