Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rutu 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mejeeji bá bẹ̀rẹ̀ sí lọ títí wọ́n fi dé Bẹtilẹhẹmu. Nígbà tí wọ́n wọ Bẹtilẹhẹmu, gbogbo ìlú mì tìtì nítorí wọn. Àwọn obinrin bá bẹ̀rẹ̀ sí bèèrè pé, “Ṣé Naomi nìyí?”

Ka pipe ipin Rutu 1

Wo Rutu 1:19 ni o tọ