Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Solomoni 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Fà mí mọ́ra, jẹ́ kí á ṣe kíá,ọba ti mú mi wọ yàrá rẹ̀.Inú wa yóo máa dùn, a óo sì máa yọ̀ nítorí rẹa óo gbé ìfẹ́ rẹ ga ju ọtí waini lọ;abájọ tí gbogbo àwọn obinrin ṣe fẹ́ràn rẹ!

Ka pipe ipin Orin Solomoni 1

Wo Orin Solomoni 1:4 ni o tọ