Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 98:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

8. Omi òkun, ẹ pàtẹ́wọ́;kí ẹ̀yin òkè sì fi ayọ̀ kọrin pọ̀

9. níwájú OLUWA, nítorí pé ó ń bọ̀ wá ṣe ìdájọ́ ayé.Yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ ayé;yóo sì fi ẹ̀tọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 98