Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 97:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Ìmọ́lẹ̀ á máa tàn fún àwọn olódodo,ayọ̀ sì wà fún àwọn olótìítọ́ inú.

12. Ẹ máa yọ̀ ninu OLUWA, ẹ̀yin olódodo,kí ẹ sì máa yin orúkọ mímọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 97